Ÿ Jowo fi rushing se Adura yi fun ara e -:
(1) Ori buruku o ni di tenant mi.
(2) Ijangbon o ni so mi di neighbour.
(3) Amubo o ni di customer mi.
(4) Osi o ni so mi di hobby.
(5) Omi inira o ni di favourite drink mi.
(6) Aisan o ni da ajo si mi lowo.
(7) Emi o ni bawon mu yara logba ewon.
(8) Tailor to nranso iponju ko ni mo size mi.
(9) Iku to npawon kakiri ko ni ka wa mole.
(10) Oloore mi ko ni fi obituary damimo.
Happy Eid el Kabir to all our muslim brothers and sisters....
May you all Experience many more of this season... Amen!!!